Arákùnrin kan ni ó kú sínú odò nígbà tí ó sòrò nípa èmí òkúnkún.
Arákùnrin tí ó n gbé ní Èkó ni ó kú nígbà tí ó lo kí ègbón rè ní Ujeme, Ekpoma, ìpínlè Edo, ní won ti rí òkú rè nínú odò ní ilé rè, léyìn tí a gbó wípé ó sonù. ...
Read More »
Arákùnrin tí ó n gbé ní Èkó ni ó kú nígbà tí ó lo kí ègbón rè ní Ujeme, Ekpoma, ìpínlè Edo, ní won ti rí òkú rè nínú odò ní ilé rè, léyìn tí a gbó wípé ó sonù. ...
Read More »Elétí Ofe, Linda Ikeji ti padà so baba omo rè, ó sì ti so wípé Sholaye Jeremi ni baba omo òun . Ó tún so wípé orúko omo òun ni Jayce Jeremi , ó ko síbè wípé… ” mò n ...
Read More »Olórin, tí ó tún jé òtòkùlú ti n se isé takuntakun láti ri dájú wípé, sínétò Ademola Adeleke di Gómìnà ìpínlè Òsun ní ibi ìdìbò tí ó n bò ní ojó àbáméta yí. Ó tí è ti n sisé takuntakun ...
Read More »Bí omo eni bá dára kí á wí, Akékòó gboyè ti ìmò tí ó n se ìtòjú ènìyàn tí a mò sí Medical Student, ti gba èbùn pàtàkí tí a mò dí Okò bògìnì àti owó goboi. Esther Azom ni ...
Read More »Gbajúgbajà a gbé òrò sórí aféfé ti gbe sí orí èro ayélujára tí a mò sí insitagiramu, láti jé kí gbogbo àgbáyé mò wípé òun ti bímo, nígbà tí ô ya àwòrán n’ílé ìwòsàn, tí ó sì pe omo máà ...
Read More »Baba Ààre Ona-kakanfo ti ilè Yorùbá tí a mò sí Iba Gani Adams ti lo. Pa Lamidi Adams tí ó ta téru nípà ní ojó Àbáméta ní ilé ìwòsàn aládáni ní ìpínlè Eko, baba kú ní ìgbà tí won fé ...
Read More »Owó pálábá Asòfin egbé APC tí ó sì jé gbòógì , tí ó sì jé asojú ilé ìgbìmò asòfin tí Ilésà ní ìpínlè Osun, ni owó bá nígbà tí ó n fi èjè wè ní àrin òru tí ó sì ...
Read More »Òyìnbó kò mà le mú ojú kúrò lórò lára àwon omoge orílè èdè Nìjíríà rárá, nítorí won mò wípé arewà ni won, won sì mo ìké oko se, bí kò bá jé béè ogún-l’ógbòn àwon òyìnbó ni ó ti fé ...
Read More »Chimamanda Ngozi Adichie ni won bí ní ojó keèdógún osù kesàn-án odún 1977 (15/09/1977), jé olùkòwé ní orílè èdè Nìjíríà, ó n ko ìtàn kékeré àti èyí tí ó pò, ó n ko èyí tí ó jé ìtàn ojú gbangban ...
Read More »Àwòrán àwon tokotayà jí ó tó di ojó ìgbéyàwó won; ìyàwó fi èyìn rè han oko láti yè é wó . Ìyàwó tí ó rewà fé kí oko rè mo ohun tí ó n kó owó lé lórí, àti wípé ...
Read More »