‘Kìí ṣe tìtorí owó ni mo ṣe fẹ́ gba Risikat padá, mo ní ìfẹ́ ẹ rẹ̀ ni ‘ Wasiu Jimoh, ọkọ Risikat tó ní ojú búlúù ní Ilọrin bá BBC Yorùbá sọ̀rọ̀, ìyàwó rẹ̀ náà fèsì. Iyawo Oloju Buluu Ẹ ...
Read More »Họ́wù! Àgọ́ ọlọ́pàá ni wọ́n tí fọmọ odó lu èèyàn méjì pa
Họ́wù! Àgọ́ ọlọ́pàá n wọ́n tí fọmọ odó lu èèyàn méjì pa Ará kò níí tán nílé alárà láé láé. À bí kínni kí á tí wí pẹ̀lú bí èèyàn méjì ti kú lẹ́yìn tí ọlọ́pàá kan fi ọmọ odó ...
Read More »Ẹlẹ́buùbọn gba ìpàdé àwọn ẹlẹyẹ ẹ̀ka ti Ọ̀ṣun
Ẹlẹ́buùbọn gba ìpàdé àwọn ẹlẹyẹ ẹ̀ka ti Ọ̀ṣun Fẹ́mi Akínṣọlá Gbajúgbajà onímọ̀ nípa ìṣègùn ìbílẹ̀ nílẹ̀ ẹ Yorùbá, tó tún jẹ́ Olóyè Àràbà nípìńlẹ̀ Oṣun. Ifáyemí Ẹlẹ́buùbọn ti gba ìpàdé ńlá àjọ̀dún ayẹyẹ àpapọ̀ ẹgbẹ́ àwọn oṣó àti àjẹ́ ní ...
Read More »Èàkàn ẹgbẹ́ òṣèlú APC mií Lanre Rasak dágbére fáyé
Èàkàn ẹgbẹ́ òṣèlú APC mií Lanre Rasak dágbére fáyé Èèkàn ẹgbẹ́ òṣèlú APC nípìńlẹ̀ Èkó, Lanre Razak ti jáde láyé lẹ́ni ọdún mẹ́rìnléláàdọ́rin. Kí ikú ó pajú èèyàn dé lójijì ti wá fẹ́ ẹ̀ kúrò ní ń tí wọ́n kíìyàn ...
Read More »Covid-19- kó̩ ló pa Babatunde Oke
Covid-19 ko lo pa Babatunde OkeOwuro oni ni won kede iku Alaga ijoba ibile Onigbongbo, Ogbeni Babatunde Oke. Gbogbo iroyin to gbee ni ajakale arun coronavirus lo paa. Won ni baba naa se aisan ranpe ni nnkan bii ose meta ...
Read More »Sáká lára dá,Bàbá Ọbásanjọ́ kò l’árùn Kofi-19
Sáká lára dá,Bàbá Ọbásanjọ́ kò l’árùn Kofi-19 Fẹ́mi Akínṣọlá Agbẹnusọ fún Bàbá Ọbásanjọ́, Kehinde Akinyemi ló fi léde bẹ́ẹ̀ nínú àtẹjáde ní Ọjọ́ Ìsinmi pé àyẹ̀wò fihàn pé kò ní àrùn Kòrónáfairọ̀ọ̀sì. Akinyemi ní Ọjọ́ Keje, Oṣù Kẹjọ, ọdún 2020 ...
Read More »Gbọ́ ń táwọn èèkàn ìlú ṣọ lẹ́yìn Búrùjí Kashamu
Gbọ́ ń táwọn èèkàn ìlú ṣọ lẹ́yìn Búrùjí Kashamu Bí ọmọ èèyàn bá wá sílé ayé, ìgbàgbọ́ Yorùbá ní pérúfẹ́ ẹni bẹ́ẹ̀ wáyé wá nájà ni. Ènìyàn ò sáà lè tajà tán kò sùn sínú ọjà, àti pé n tí ...
Read More »A ti gba 800 bílíọ̀nù owóòlú tí wọ́n jí kó, àwọn 1,400 ti dèrò ẹ̀wọ̀n– Lai Mohammed
A ti gba 800 bílíọ̀nù owóòlú tí wọ́n jí kó, àwọn 1,400 ti dèrò ẹ̀wọ̀n– Lai Mohammed Ẹdìyẹ ń làágùn, ìyẹ́ ni kò jẹ́ kó hàn.Ìjọba àpapọ̀ ti sọ pé òun ti gba owó tó lé ní ẹgbẹ̀rin bílíọ̀nù náírà ...
Read More »Fayemi kó àjàkálè̩ àrùn covid-19
Fayemi kó àjàkálè̩ àrùn covid-19 Gomina kayode Fayemi ti ipinle Ekiti to darapo pelu awon gomina to ko ajakale arun coronavirus.Fayemi kede eyi lori ero Twitter re pe saka ni ara oun da sugbon ayewo fihan pe arun naa wa ...
Read More »