Òní laó roko létí opónÒla laó sákà lágbèrùKùtùkùtù ìrèní laó he erè nígbódù oòniKáyáa múlé pontíKámú òdèdè rokàKáfi agbada dínranÀwèje wèmu nípón omodé wòyí lójúÒrìsà lópabuké tánLódákún sábaro nídìíOmo-ojo húnsáré gíríjo-gíríjoOmo-ojo húnsáré gìrìjo-gìrìjoIlé-ifón kògba obàtáláÈlàgboro kògba òrìsàOjúgboro ni tàfínÈlàgboro ni ...
Read More »Òyèkú bìwòrì
Òyèkú bìwòrì,Gbóró,gbóró,gìdì ? òyèkú b’ìwòrì?Ajan gbóró gìdìAdífáfún lájosìnOmo ab’oya ríreÈyí tio bo òrìsà obìnrin làÈròpo àti tòfàB’ifá bá..bíni níbèOya ni ko maa bo ~Translation ~ Òyèkú bìwòrìGbóró gbóró gìdìAjan gbóró gìdìCast ifá for lájosìnThe one that worship oya with blessingsThe ...
Read More »Àwọn ilé mi, ọkọ̀ 12, ọmọ àti ènìyàn méje pẹ̀lú ₦500m ni mo sọnù ní Igangan – Seriki Fulani
Àwọn ilé mi, ọkọ̀ 12, ọmọ àti ènìyàn méje pẹ̀lú ₦500m ni mo sọnù ní Igangan – Seriki Fulani Fẹ́mi AkínṣọláSeriki Fulani ní ìlú Igangan níjọba ìbílẹ̀ Ibarapa nípìnlẹ̀ Oyo, Alhaji Salihu Abdulkadir ti fẹ̀sù kan pé ajafẹ́tọ ọmọ Yorùbá, ...
Read More »Gómìnà Eko, Sanwó-Olú jẹ́jẹ̀ẹ́ ìrànwọ́ fún àwọn ọlọ́pàá tó lùgbàdi
Gómìnà Eko, Sanwó-Olú jẹ́jẹ̀ẹ́ ìrànwọ́ fún àwọn ọlọ́pàá tó lùgbàdi Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé wọ́n ní ìgbẹ̀yìn làásìgbò kan kìí bímọ tó rọ̀. Làásìgbò tó wáyé ní ìpínlẹ̀ Èkó láìpẹ́ yìí ti mú kí Gómìnà ìpińlẹ̀ náà, Babájídé Sanwó-Olú ó pàsẹ ...
Read More »Osa Eleye!
Ogbón kan mbe níkùn Asá,Ìmòràn kan mbe níkùn Àwòdì,Òkàn níkùn e, Òkàn níkùn mi,Òkàn níkùn ara wa,Diafun Òrúnmìlà,Baba ñ loree b’awon Àjé mulè nígbó Olúkórómójó,Wón ní kílódé,O ní nitori kí Ayé le gunO ní nitori kí igba le rò
Read More »EndSARS: Olórí ilé aṣojú-ṣòfin ní ìṣúnà 2020 gbọdọ̀ pèsè owó fún ASUU bí bẹ́ẹ́kọ̀…
EndSARS: Olórí ilé aṣojú-ṣòfin ní ìṣúnà 2020 gbọdọ̀ pèsè owó fún ASUU bí bẹ́ẹ́kọ̀… Fẹ́mi Akínṣọlá Olórí ilé asojú-sòfin nílẹ̀ wa, Fẹ́mi Gbàjàbíàmílà ti sòṛọ̀ nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó se kókó tó n wáyé nílẹ̀ wa, paàpá ìwọ́de EndSARS. Gbàjàbíàmílà, ...
Read More »Jàǹdùkú pa ọlọ́pàá méjì, jó àgọ́ wọn mẹ́wàá, báńkì mẹ́ta, jí ọ̀pọ̀ owó l’Ékó -iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
Jàǹdùkú pa ọlọ́pàá méjì, jó àgọ́ wọn mẹ́wàá, báńkì mẹ́ta, jí ọ̀pọ̀ owó l’Ékó -iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, ìjàngbọ̀n kìí dúró síbi tó bá rọ̀, bí kò ṣe ibi tó bá le koko. Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ...
Read More »Ìṣẹ̀lẹ̀ Lekki, Ẹ̀ẹ̀mejì ni mo pe Ààrẹ Buhari lánàá , àmọ́ ń kò ri bá sọ̀rọ̀ – Sanwo-Olu
Ìṣẹ̀lẹ̀ Lekki, Ẹ̀ẹ̀mejì ni mo pe Ààrẹ Buhari lánàá , àmọ́ ń kò ri bá sọ̀rọ̀ – Sanwo-Olu Fẹ́mi Akínṣọlá Bí ọ̀rọ̀ ńlá kò bá tíì tán èèyàn ńlá kò ní tíì sinmi àròyé Sanwo-Olu tíí se Gómìnà wọn ní ...
Read More »#EndSARS: Obasanjọ, Ọọ̀ni sọ̀rọ̀ lórí ìwọ́de tó ń lọ lọ́wọ́
EndSARS:Obasanjọ, Ọọ̀ni sọ̀rọ̀ lórí ìwọ́de tó ń lọ lọ́wọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Àgbà tí òye yé kan kìí wà lọja, kí orí ọmọ tuntun wọ́, ìdí rèé tí àwọn àgbà kàn-aǹ-rìn méjì nílẹ̀ Yorùbá fi forí korí lórí ìwọ́de EndSARS tó ...
Read More »Buhari kí Obaseki kú oríire
Buhari kí Obaseki kú oríire Ààrẹ Muhammadu Buhari ti ránṣẹ́ kú orííre sí Godwin Obaseki lẹ́yìn tó jáwé olúborí nínú ìdìbò gómìnà tó wáye lónìí nípìnlẹ̀ Edo. Obaseki tó jẹ́ olùdíje dupò gómìnà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ló fi ìdí ...
Read More »