Olotu:kini ikan tori tofi ni o le gba ki iya gbe pelu re,gbogbo awon eyan loti ba e so,o ko,o loni gbo,won tun gbe e wa sori afefe,agidi yi nan lotun lo.Kini ikan to sele gan. Iyawo:seri olotu,mole gba ki ...
Read More »Olojo Ibi Toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alfa Ola Akeem Totofun’un ti won je okan pataki ninu ebi Ooduarere. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu ...
Read More »Ojumo Ire
B’ojumo ba mo .. Ooye a la #peregede.. A D’ifa fun Peregede tii se yeye #Ojumo . A KU OJUMO #Ojumo to mowa Lonii. #Ojumo_Ire gbogbo ni yoo je funwa lase Oba mi Oke .
Read More »Elesin Oyan
Iba Orunmila Bara Agbonniregun; Elesin Oyan; Adagbaa Ojomu; Gbolajoko Omo Ere l’apa; Baba Okinkin ti n m’eyin erin fo; Odudu tii du ori emere ti o je ko fo; Atori eni ti ko sunwon se! Iba Baba o!
Read More »Oniwowo ado! Baba dakun ma na mi o! Aase!
OBALUAYE!!!!!! OOOOOOO cc- Babalawo Ifakayode Oyedele Osaifa
Read More »Foto ode’oni – 13.07.2016
Saheed osupa akorede ati baba wande.
Read More »Ejowo eni to ba mo olorin yi ko ko oruko re
Edakun kini oruko olorin yii
Read More »Gbogbo wa ni o bo ikin la! Aase!
IFA NI Asese roko agbe adabi akiti ohun obo Adifafun Ajala yobo Ikin la lese oke ebo won ni kose ogbebo ni be osebo bi kasai bokinla olowo Ajala bi kasai bo Ikinla emin ateyin ololufemi gbogbo wa labo ikin ...
Read More »Ogulutu Oro Toni – 09.07.2016
Hummmmmmmm igbiyanju lagbe ngba Olohun lomu isu ta #woo_orewa Nje o mo pe eni tio sun(sleep) lo nsun(move)????? ??? Gbiyanju lati tesiwaju loni majeki ijakule re fao seyin nigbesi aiye re #gbomi_dada Koseni tio ni #sugbon tie gboju re kuro ...
Read More »Akara Imora’n toni – 09.07.2016
*Emi ko ni ku saaju ojo ayo mi.*Emi ko ni fi ewon logba.*Iji aye ko ni gbe mi lo(Ase Edumare). …………. #AKARA_IMORAN : Gbiyanju lati ni iwe iranti fun awon olooore re; ki o si gbiyanju lati fa iwe asise ...
Read More »