Home / Àṣà Oòduà (page 152)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Ogo Omu-Aran Ni Ipinle Kwara Pe Eni Odun Mokanlelogota (61)

Oni, 27-09-2015, ni Bisoobu Dafiidi Olaniyi Oyedepo pe eni odun mokanlelogota (61). Omo bibi Omu Aran ni ipinle Kwara ni i se, oun kan naa ni oluso aguntan agba fun ijo Living Faith Ministry to kari aye pata. Onkowe ni, olukoni oro ...

Read More »

Won Ya Aso Iyi Saraki Niluu Ilorin Lojo Odun Ileya

Okuta ati ogulutu ni awon eniyan bere si ni so lu aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, laaaro oni nibi to ti fe kirun yidi odun ileya niluu Ilorin Afonja. Bi awon eniyan se n ju okuta bee naa ...

Read More »

Kilode Ti Ogbeni Bukola Saraki Fi N Paro?: O paro Nile Ejo Tiribuna, O Tun Paro Fun Omo Naijeria

Ni ile Yorubawa, ti omo kekere ba n paro, awon agba gba wi pe iru omo naa le jale tabi ko ti maa jale. Lara esun metala ti eka onidajo ti Code of Conduct Bureau, Code of Conduct Tribunal gbe ...

Read More »

Se Eyin Ri Iru Aso Igbeyawo Bayii Ri?

E leyii tun leku!

Read More »

Ohun Ti E Ko Mo Nipa Igbeyawo Obasanjo Ati Iyawo Re, Mama Iyabo

Ki e to tesiwaju lati ka abala keji iroyin yii, maa royin ki e ka abala kinni na. Eleyii yoo fun yin ni oye ibi ti alaye naa ti bere. E le ka iroyin naa ninu linki isale yii: Bi ...

Read More »

Foto Yii Lo N Se Afihan Ohun Ti Awon Omo Nigeria N Ro Nipa Ojo Ola Nigeria

Nje awon eniyan omo Nigeria si ni igbagbo wi pe Naijeria sile goke agba?  E se ayewo linki isale yii lati ka ero awon omo Nigeria:

Read More »

Olatunbosun Oladapo Patan Ayo Leni Odun Mejilelaadorin (72)

Ojo ibi baba tun ti wole de. Ki n maa paro, owo mi n gbon, mi o si mo ohun ti maa ko gan-an lati fi ki baba rere. Mi o tile mo iru agbekale asanyan oro ti mi o ...

Read More »

Hannah Idowu Dideolu Awolowo Ti Lo Ba Oko Re Lorun

Won ti bere igbaradi, inu osu kokanla odun yii ni won pinnu lati se ojo ibi Ogorun (100) Odun Yeye Oodua. Sugbon iku seka, iku doro, iku mu Hannah Idowu Dideolu Awolowo lo leni odun mokandinlogorun (99).   Ki Edua oke ...

Read More »

Bukola Saraki Wo Gau: Won Pada ‘geti’ Maanu Naa

Leyin awon esun bi metala ati esun iro funfun ti Bukola Saraki pa nipa jijewo dukia to ni. Ile ise ijoba apapo, eka ti awon onidajo ti pase ki ile ise olopaa ile yii, labe akoso ogbeni Solomon Arase lo ...

Read More »

Irawo Olorin Ti Won Yin Ni Bajinatu Lodun 2007 Ti Pe Omo Ogoji (40) Odun Lonii

Osu kewaa odun 2007 ni awon afura si kan gege bi agbanipa bere si ni rojo ibon fun Innocent Idibia ni ibudoko Cele to wa loju ona masose Oshodi si Apapa to wa niluu Eko. Sugbon gege bi Ayinla Omowura ...

Read More »