Oya òpèré, Ekùn oko asè’ké Oya má bá mi jà Mi ò l’ówó aféfé ńlé Èmi ò rí eni tí yó ràgàn, ràgàn bí Oya ní òde ìpo Kò séni tí ó ràgàn ràgàn bí Oya lótù ifé Oya lo ...
Read More »E wá wo isé tí Àlùbósà.
_Sebí ohun tó bá jọnilójú, ni Yorùbá n sọ wí pé ó yanilẹ́nu. *Àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ sáyẹ́nsì kan ní ìlú CHINA ti jẹ́ kó yé wa wí pé ìwádìí tuntun tí fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wí pé ÀLÙBỌ́SÀ (kò báà ṣe ...
Read More »Eniyan koni rajo kofi orire kale sile ibiti aba koriwa mase pada leyinwa oo
Ori mi Apere isedami Ajifobi kan Amuni wale aye magbagbe Eni Orimi gbemi bose gbe omo alara tofidade owo isedami gbemi bosegbe omo ajero tofi tepaleke orimi gbemi bose gbe omo orangun ila tofidi eni apesin pitipiti mogbani Adurafun wape ...
Read More »Ooni ti ile-ife ní ìdí òpe àgùnká .
Ayeye Odún ifá àgbáyé eléyìí tí ó wáyé ní òkè-ìtase ní ilú ilé-ifè. Ooni rèé ní ìdí òpe àgùnká ní ibi tí mùtúmùwà ti ń se àdúrà sí ìsèdá won, kódà oba náà kò jáfara.
Read More »Ìwúre Òṣù Tuntun
Bí ÒṢÙ bá yọ loke terutọmọ niiri, omi ajipon kiiru, ninu ÒṢÙ kẹfa yi aye gbogbo wa yio toro minimini, bi Ọgẹdẹ ba pọn ará aa dẹẹ, ara oni ni emi àti Ìwọ oluka àtèjìṣẹ mi yi, àtijẹ atimu koni ...
Read More »A kú òsè jàkúta.
Sango oooo Olukoso ayanran ina Ina loju, ina lenu Sangiri, lagiri Olagiripapa figba edun bo Eefin ina la n da laye Ina nbe lodo oko mi lorun Abaabe ooooooooo Abaabe laba Se fun SANGO Emi Se SANGO labaabe Agbenajo, Agbenayan ...
Read More »Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó tokotayà yí ti won pàdé nígbà tí won ń sin orílè èdè won lówó ní odún mérin séyìn.
Arábìnrin Nìjíríà kan tí a mò sí Rosemary nípa eni tí yó sèsè di oko rè Láìpé odún màrún-ùn séyìn, nígbà tí won ń sin orílè èdè won lówó ní Kaduna ti pín àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó ...
Read More »Fúlàní darandaran pa àwon èèyàn ní ojú ònà Makarda ní òpópónà Makarda.
Óní òun so gbangba gbàngbà ni Láì bèrù enikéni :báyìí ni Adamu Donald Dekwagh, wípé enikéni kò gbodò sùn nígbà tí igbákejì Ààre orílè èdè lo kí won ní Benue ní ànà yí tí àwon wòólì méjì àti darandaran pa. ...
Read More »Òdókùnrin kan ní àwon olópàá yin ìbon pa nígbà tí won fé parí ìjà ní Ajegunle.
Òdókùnrin kan tí a gbó wípé ó jé omo ogún odún ni a gbó wípé won fi èsùn kàn àwon olópàá Látàrí ìbon tí won yìn pa Òdókùnrin yí, nígbà tí won ń parí ìjà lówó láàrin àwon ìkò ológun ...
Read More »Paul Okoye níbi tí ó ti ń bá àwon ìbejì rè Nadia àti Nathan seré .
Paul Okoye tí a mò sí Rude boy ni ó pín àwòrán tí ó rewà yí nígbà tí ó ń lo àsìkò pàtàkì pèlú àwon ìbejì rè Nadia àti Nathan seré èyí tí ó pín sí orí èro ayélujára (instagram)..
Read More »