Bi yahoo-yahoo ni won ni abi ogun oloro ni won gbe, ta lo mo. Sugbon o daju wi pe, eni to n sise gege bi omoluabi ko ni da iru eleyii lasa wo laelae. Ori ayelujara ni aworan yii ti bere ...
Read More »Obirin kan bi omo sinu Keke Maruwa
Onise ara ni Olorun oba. Omobirin alaboyun kan lo bere si ni robi ninu Keke Maruwa ni akoko ti won gbe lo si ile iwosan lati lo bimo niluu Enugun. Eyi to ju ibe ni wi pe, ojo odun lo ...
Read More »Won ti fi Ladoja je Osi Olubadan
Won ti fi Senator Rashidi Adewolu Ladoja je Osi Olubadan lonii (01/01/16) ni aafin Oba Samuel Odulana Odugade, Olubadan tile Ibadan.
Read More »E pade awon ore yin nibi
Orisiirisii ona ati idi pataki ni awon eniyan fi n yan ore tuntun. Awon kan fe alajoso, awon kan fe alabaro, awon kan si n fe eni ti won yoo jo maa takuroso lasan. Eyiowu ko je, ore dun ti ...
Read More »Kini ero yin nipa awon obirin to ga fiofio?
Mo mo wi pe awon obirin maa n fe lati fe awon okunrin to ba ga. Sugbon mi o mo boya bakan naa lori pelu awon okunrin nipa fiferan awon obirin to ga fiofio. Se kii se wi pe giga ...
Read More »Odun Iwude Ijesa: Gbogbo aye pejo saafin Owa Obokun
Ese ko gbero lojo Satide to koja yii niluu Ilesa nibi ti tonile talejo ti gbe pejo lati sodun Iwude Ijesa laafin Owa Obokun Adimula ti ile Ijesa, Oba Gabriel Adekunle Aromolaran. Gege bi a se gbo, ayeye odun Iwude ...
Read More »Odun 2016 yoo dun bi oyin: E ku odun tuntun
E ku odun tuntun. Odun ayo ati igbega ni yoo je fun gbogbo wa. Ase. Odun 2016 yoo dun bi oyin. Bee ni. E je ki eleyii je ero yin. Kosi tun maa jeyo ninu awon oro enu yin nigba ...
Read More »Igbeyawo omo Adewale Ayuba fakiki
Idunnu obi ni ki omo o yan ko si yanju. Omo taa to, to si duro gbeko ni i pada di omo gidi lowo awon obi re. Eyi ni a le pe ni itan Tiwalade Ayuba lowo baba re. Ayo ...
Read More »Omiyale-agbara ya soobu ti se ijamba niluu Oba Biritiko
Aimoye dukia lo ti sofo bayii latari iji nla pelu agbara ojo ti n wo odindi moto sare ni ilu England bayii. Isele buruku yii lo waye latari ojo alagbara kan to si lule to si bere si ni se ...
Read More »