Orisun Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu-Ode *Komisanna lo pase fun awon olopaa Olayemi Olatilewa Owo awon olopaa ipinle Ogun ti te awon afura si kan gege bi omo egbe okunkun ni Ijebu-Ode. Gege bi atejade ...
Read More »Fayose kede nomba ero ibanisoro re fun awon eniyan ipinle Ekiti
Gomina Ayo fayose ti kede nomba ero ibanisoro re lori eto olosoosu kan to maa waye lori redio ati telifisan ipinle Ekiti, “E PADE GOMINA”. Lori eto yii ni gomina ti n jiyin awon ise iriju re fun awon eniyan ...
Read More »Se eru nla FIFA ko ni wo Issa Hayatou lorun?
Bi o tile je wi pe iriri odun metadinlogbon (27) ni Ogbeni Issa Hayatou ti ni nipa didari ajo to n ri si ere boolu ile Afirika, Confederation of Africa Football. Sibesibe awon ololufe ere boolu ni awon ilu okeere ...
Read More »Niluu Abeokuta, apata wo pa iya ati awon omo re
Niluu Abeokuta, apata wo pa iya ati awon omo re. Olayemi Olatilewa Apata kan ti n be loke tente ni agbegbe Iberekodo niluu Abeokuta ti ye lule to si seku pa iya ati awon omo re. Bi eniyan ba je ...
Read More »ILERA LORO: Bi a se le se itoju ehin enu wa
#Oniroyin @OlayemiOniroyin Aridaju iwadii ti fi ye wa wi pe osan orombo dara pupo ni mimu eleyii to n fun erigi ehin wa ni agbara. Mimu osan orombo ran erigi lowo lati le mu ehin enu wa duro daada nipase ...
Read More »Obirin to bi ibeta ni yii leyin ti Boko Haram gba ile lowo won
Arabirin yii bi ibeta (omo meta) ni ipago ti won pese fun awon eniyan ti Boko Haram so di alainile lori to wa ni Bama ni ipinle Borno. @OlayemiOniroyin
Read More »Ijamba oko waye ni Victoria Island lonii
Ijamba oko to waye lonii ni agbegbe. Ozumba Mbadiwe, VI, niluu Eko. Oko ajagbe akeru naa run mo awon oko bi merin kan nigba ti bireki re ko muu mo. Enikeni ko fara pa, dukia lasan lo sofo.
Read More »Obalufe, igbakeji Oba Okunade Sijuwade ti dagbere faye lonii
Obalufe ti Iremo-Ife, Oba Samuel Omisakin, eni to kangun si Ooni Ile-Ife, Oba Okunade Sijuwade gege bi igbakeji, to tun je olori awon afobaje ti ilu Ile-Ife naa ti dagbere faye lonii [15-10-15].
Read More »Owo awon olopaa te ole ajipata ati komu niluu Ibadan
Ero o gbese ni olu ile ise awon olopaa ipinle Oyo to wa ni Eleyele nigba ti won se afihan awon igara olosa ajipata ati komu gbe fun awon oniroyin niluu Ibadan. Awon ole bi merin yii lagbo wi pe ...
Read More »#OGULUTU: Olaju ti so ogbon aye atijo di omugo patapata
E ku asiko yii eyin eniyan mi, ko to di wi pe n maa se alaye ara mi tabi abala Ogulutu to je tuntun to gori Iwe Iroyin Owuro. E je n sare bi yin nipa oun ti won pe ...
Read More »