Ogulutu Oro Toni
si gbogbo okunrin hummmmm moseba gbogbo obinrin ooooooo………eyi ni oruko meta ti OLOHUN so wipe awon OBINRIN nje ti gbogbo OKUNRIN SI GBODO MO,,, Akoko:AWAWU Ekeji: ONIGBAGBE ENIYAN Eketa: ONIFENU # wo ore wa majeki ohun ti obinrin re tabi ...
Read More »Eba Wa Da Si Oro Yii ooo
Eyin Okurin Se ele gba wipe ki Iyawo yin je oga yin ni ibi ise ?
Read More »Iroyin Ere Idaraya Lerefee (02-04-2016)
Ajo to n mojuto #LEAGUE awon obinrin nile wa “NWFL kede ola ojo keji osu kerin gege bi ojo ti idije boolu LEAGUE obinrin fun saa tuntun yoo gberaso kaakiri ile wa. ……….. Emi ati awon agbaboolu mi nlo si ...
Read More »Ounje Emi Fun T’ooro Yii (02-04-2016)
………………………………………………………. Iwe-Iroyin #AYEKOOTO_MAGAZINE fun T’osu kerin ti jade sita bayii, #Ogorun naira #100 ni beere fun tire lodo #VENDOR nibi-kibi …………………………………………………………… AMOYE TONII : #ARABINRIN_FOLASHADE_TEMITOPE ………………………………………………………….. …………………………………. HUN !!! #Iya to je omo f’ogun #Odun .. #Osi to ta omo ...
Read More »Iwure Owuro 02-04-2016
E MAA WI TELE MI : ……. *Edumare ma je ki n soore daran. *Oluwa ma je ki n gbalejo oran. *Edumare ba mi segun elenini. *Oluwa ran alaanu si mi. *Edumare gba mi lowo alaroka. *Oluwa dakun rojo ibukun ...
Read More »Edurona ibo la nba oro epo lo ni 9ja bai ooooo … ?
Elo leyin nra epo ladugbo yin????
Read More »Idile Alayo: Oro owun si fe toju sumi
A ki gbogbo wa ku jimo oloyin toni a si ki wa ku abo sori eto Idile Alayo ti ose yi, gege bi ise wa atejise kan ti a ri gba lati owo okan lara won ololufe eto yi ni ...
Read More »Àsodúnmódún ní í sawo àsodúnmódún..
Àsosùmósù ní í sawo àsosùmósù, Odún kì í dun ká má rìí ohun àjòdún. Olódùmarè á soore àrí tókasí fún ire láyé e eni iyì Oba Abel Simeon Olúwafémi bí e ti lé ódún kan lónìí. Àlékún owó, Àlékún ogbón, ...
Read More »Iwure Owuro 27/03/2016
:::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::: E MAA WI TELE MI : ……… *Edumare ma fi omo pa mi lekun. *Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun. *Ogun aye koni bori mi. *Iji aye koni ja lu mi. *Inira ati idaamu, koni je temi. ...
Read More »